Letra / Lyrics
Obt — Shoday
Oh, baba yẹ, dáhùn s'ọrọ mi Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi One big transaction, tó ma change story mi Malaika tó n gbé're, jọ wá gbé'rẹ s'odo mi Oh, babá ye, dáhùn sọrọ mi (Ob—, Obah) Oh my maye, ma ma k'ohùn mi (wah dem a say?) One big transaction, to ma change story mi Malaika tó n pín'rẹ, jọwọ pín'rẹ d'odọ mi Wọn ni Naija ṣi ma dùn, but you dey America E go better la ti n gbó la t'aye Abacha Owo t'ọmọde bá kọ'rí, á fi jẹ akara If I see first money, mo ma sá lọ Canada Oh, baba ye, dáhùn s'ọrọ mi (Shoday, kí lo dé?) Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi (mm) One big transaction, to ma change story mi Malaika tó n pín'rẹ, jọwọ pin're d'odo mi (oh, babá yè) Oh, babá ye, dáhùn s'ọrọ mi (dáhùn s'ọrọ mi) Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi (ma ma k'ohùn mi) One big transaction, tó ma change story mi (ehn) Malaika tó n pínrẹ', jọwọ pin're d'odo mi (oh, baba yè) Ibí e ní gbégbé kò ma gbé, ibè ló ma gbé (ibè ló má gbé) Ọjà to ni gbégbé kò ma gbé, gbogbo ẹ ló ma gbé (gbogbo ẹ ló ma gbé) Purple Haze ninu brown rizzler, high me my canister Oh my maye ye-ye, wa gbé mi trabaye, ye-ye Ayy, it's going, it's going, olomi kò ní s'oṣi, kò ní s'ofo They're trolling their father, I'm stoning pẹ'lú kpoli, pẹ'lú coco Kò sí problem, kò sí yawa, kò sí story, kò sí glory, ọmọ ologo Ah, dorime fún ọmọ ọpẹ (dorime fún ọmọ ọpẹ) Ọmọ oro mi wá pẹ (ọmọ oro mi wá pẹ) Oh, baba ye Oh, baba ye, dáhùn s'ọrọ mi (dáhùn s'ọrọ mi) Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi (ma ma k'ohùn mi) One big transaction, tó ma change story mi (ehn) Malaika tó n pín're, jọ'wọ' pín're d'odo mi Oh, baba ye Oh, baba ye, dáhùn s'ọrọ mi (dáhùn, dáhùn, dáhùn; dáhùn s'ọrọ mi) Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi (ma ma k'ohùn mi) One big transaction, to ma change story mi (ehn) Malaika tó n gbé'rẹ, jọ wá gbé'rẹ d'odo mi (gbé-gbé'rẹ d'odo mi)
Com assinatura de Shoday, "Obt" chegou ao YouTube em 6 de fevereiro de 2026 e já soma 2,9 mi de visualizações. São 13 mil curtidas até agora, numa duração de 2:50. Dê play e a sequência segue automaticamente com outras músicas da parada.
Veja todas as paradas em Músicas Mais Tocadas e explore todos os estilos musicais.